Ẹ́mbáásì Amẹ́ríkà Kìlọ̀ Ìkọ̀lù Òjìjì Ní Moscow
Ẹ́mbáásì Amẹ́ríkà ni Russia ti ṣe ìkìlọ pé awon esinoòkọkú lérò ìkọ̀lù Òjìji sí ìlu Moscow ni kete ti Russia ti sọ èròngbà ibọn yíyin sí synagogue láti ọwó àwọn adìhámọ́ra ogun lati ọdọ Afghan ti Islamic State di otubantẹ́.
Ẹ́mbáásì náà ti sọ ni ọ̀pọ̀ ìgbà pé kí gbogbo ọmọ ilẹ Amerika fi ilu Russia sile ni kiamosa, wọn sọ pé kí awọn eniyan mase lọ sí ibí ere tàbí ibi ti èrò pọ̀ sí, ki won si kíyèsi àyíká wọn.
Ẹ́mbáásì sọ pé ki awọn ènìyàn kiyesara torí èròngbà ibi awọn esinokoku,
o pé tan wakati méjìdínláàdọ̀ta to n bọ̀ latari awọn oniṣẹ ibi, Ẹ́mbáásì sọ eyi lori ero ayelujara wọn
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san