Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbárádì Ìdánwò JAMB Tí Ọdún Yìí Ṣetán Láti Bẹ̀rẹ̀

257

Àjọ tó ń rí sí ètò ìdánwò láti wọlé sí Ilé-ìwé gíga Yunifásítì (Joint Admission and Matriculation on Board JAMB) tí sọ wípé ìdánwò ìgbárádì tí ọdún yìí, ìyẹn ‘2024 Mock Unified Tertiary Matriculation Examination, UMTE’ yóò wáyé ní Ọjọ́bọ̀ ọjọ́ kéje Oṣù kẹ́ta ọdún 2024, pẹ̀lú ìdánilójú wípé gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n yóò ṣé ìdánwò náà ní wọ́n gbá láàyè látí wọ́ inú gbọ̀ngán ìdánwò pẹ̀lú ‘HP pencil’ lásán fún ìṣirò nọ́mbà tí wọ́n bá fẹ́.

Agbẹnusọ tí JAMB, Dókítà Fabian Benjamin nínú ọrọ̀ kàn sọ pé àlàyé náà dì pàtàkì lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìbéèrè látí ọdọ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àtí gbogbo ènìyàn nípa pé bóyá igbalaye wà fún ìkọ̀wé HP nínú gbọ̀ngàn ìdánwò bí òun èlò.

O ṣé àkíyèsí pé Ìgbìmọ̀ náà tí fí òfin dé lílo àwọn ìkọ̀wé àtí àwọn òun èlò mìíràn nítorí àwọn oún tí wọ́n ń ló àwọn òun èlò wọnyí fún.

Comments are closed.

button