Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti fọwọ́ sí yíyan Engineer Oluwagbenga Ajiboye láti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Olùdarí àgbà fún ilé iṣẹ́ apinna ní Nàìjíríà,(Transmission Company of Nigeria TCN).
President Bola Ahmed Tinubu appoints four Nigerian professionals as Executive Directors of TCN:
1. Engineer Oluwagbenga E.A. Ajiboye – Executive Director, Transmission Service Provider
2. Engineer Nafisatu Asabe Ali – Executive Director, Independent System Operations
3. Ochije… pic.twitter.com/Co14Q9RYdg
— Voice of Nigeria (@voiceofnigeria) March 1, 2024
Ààrẹ náà tún yàn Engineer Nafisatu Asabe Ali gẹ́gẹ́ bí Olùdarí àti Aláṣẹ tí Àwọn ilé-iṣẹ́ òmìnira ‘independent System Operation’, Ochije Ogini Chukwuka gẹ́gẹ́bí Olùdarí àti Aláṣẹ tí Owó àtí ètò owó, àtí Abiodun Foluso Afolabi gẹ́gẹ́bí Olùdarí àti Aláṣẹ tí Àwọn ilé-iṣẹ́ ‘Human Resources and Corporate Services.’
Àlàyé náà tí Agbẹnusọ tí Ààrẹ, Ajuri Ngelale, tí f’ọwọ́ sí, sọ pé àwọn tó gòkè lẹ́nu iṣẹ́ dè ipò yìí, yóò tẹ̀síwájú fún ọdún mẹ́rin mìíràn.