Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu sọ pé Nàìjíríà ti gbáradì láti ta kókó ìbásepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Brazil
Ààrẹ sọ ọ̀rọ̀ náà nígbà tí ó pàdé Ààrẹ Luiz Inacio Lula da Silva ti Orílẹ̀-èdè Brazil, ní ìlú Addis Ababa, Orílẹ̀-èdè Ethiopia, ní ọjọ́ Ajé
Ó sàpèjúwe ìbásepọ̀ náà gẹ́gẹ́ bí èyí tí yóò mú ànfààní bá ọrọ̀ ajé Orílẹ̀-èdè méjéèjì náà