Take a fresh look at your lifestyle.

Tí Ìjọba Bá kọ̀ Láti Mú Àdéhùn Tí Wọn Bá Ẹgbẹ́ Òsìsẹ́ Ṣe, NLC Yóò Gúnlè Ìwọ́de Ọlọ́jọ́ Méjì Ní Ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ́n Àti Ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọ́n Oṣù Kejì Ọdún 2024.

148

A ó gùnlé ètò ìwọ́de Ọlọ́jọ́ méjì ní oṣu ti a wa yii tí ìjọba kò bá mú àdéhùn tí wọ́n ṣe pẹ̀lú wa ṣẹ.

Ààrẹ ẹgbẹ́ NLC Joe Ajaero ti ní ẹgbẹ́ oṣiṣẹ yóò gunle ètò ìwọ́de Ọlọ́jọ́ méjì ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ́n àti Ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọ́n Oṣù Kejì Ọdún 2024.
oṣù yìí tí ìjọba kò bá mú àdéhùn tí wọ́n ṣe pẹ̀lú wọn ṣẹ.

Ààrẹ tun tẹ̀síwájú pé ọ̀nà kan ti ìjọba àpapọ̀ fi le máa ję kí àwọn gunle ètò ìyansẹ́lódì ni ki ìjọba mú àdéhùn tí ó bá ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ṣẹ ní ọjọ́ keji oṣù kẹwàá ọdún 2023.

Ààrẹ ní kété tí ọjọ́ kejílélógún oṣù kejì tí wọ́n fún ìjọba àpapọ̀ bá pé, tí ìjọba sì kọ láti mú àdéhùn tí wọ́n ṣe ṣẹ àwọn yóò se ìwọ́de Ọlọ́jọ́ méjì ní Ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gbọ́n Àti Ọjọ́ Kejìdínlọ́gbọ́n Oṣù Kejì Ọdún yìí.

A o ri i pe ni ọdọọdun ni ìjọba ń se àtúnṣe lórí owó osù àwọn oṣiṣẹ.

Comments are closed.

button