John Mahama, to jẹ adari ẹgbẹ́ olóṣèlú National Democratic Congress, so wí pé Sísùn Ìdìbò Síwájú ko le ṣẹ e ṣe
Èyí di mímọ nígbà tí wọn n fi ọ̀rọ̀ wa lẹnu wò ni Accra.
Wọn ni ki won sún eto idibo siwaju sí ìparí ọdún yìí, ṣugbọn àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú tó kún tako àbá náà.
Wọn ní kọkọ ti won fi sún síwájú ní wí pé kí àwọn ba leè ni ọpọlọpọ àsìkò láti Gbaradi fún ìdìbò naa