Take a fresh look at your lifestyle.

Fena Gitu Di Akọrin Tuntun Ti EQUAL Africa Fún Ti Osù Kejì

173

 

Spotify, ti dárúkọ akorin ọmọ ilẹ Kenya, Fena Gitu, gẹgẹ bí akọrin ‘EQUAL Africa’ ti oṣù Kejì yìí.

Èyí di mimọ̀ ninu akọsilẹ láti ọdọ òṣèré Spotify àti oludari Label Partnerships láti ìlà Oòrùn Áfíríkà, Monica Kemoli-Savanne, to gbe jade ni ọjọ Ọjọ́rú.

Bi Kemoli-Savanne se sọ, EQUAL Africa
ni àfojúsùn sí àwọn obìnrin Olorin, wọn fe kí ògo wọn jáde nínú orin lai fi ẹ̀ya, èmi ju ọ́ ìwọ o ju mi, ọkunrin ni mi tabi obinrin se.

Obìnrin náà tún sọ pé, ètò náà wa fún atilẹyin fún àwọn elere ti wọn ti mọ̀ tabi ti wọn ko ti mọ̀ daradara èyí to mun wọn lọ́mún.

O fi kun pe ìjáde àwọn obinrin ti a leè ri Olórin jẹ́ ìwúrí lati gbé awọn ogo to ṣẹṣẹ ni dide jáde, yóò sì tún ran iran tuntun míràn lọwọ.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button