Take a fresh look at your lifestyle.

Kò Sí Aburú Nínú Ká Máa Polongo Ìbò De Ọdún 2027- Sénétọ̀ Ashiru

189

Igbákejì Olórí àwọn Sénétọ̀ ninu ile igbimọ aṣòfin, Senator Lola Ashiru
ti sọ pe òun ko ri ohun to burú nínú pé olóṣèlú ki olóṣèlú máa polongo ìbò sílẹ fún ọdún 2027 láti ìsisìyí lọ.

Botilejepe òun kò leè lọwọ nínú ipolongo bẹ́ẹ̀, ó sọ bi ọkàn rẹ ṣe rí nípa èyí nígbà ti o n fọ̀rọ̀wérò pẹlu àwọn oníròyìn ni ọ̀fà, ìlú rẹ ní ipinlẹ Kwara.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button