Take a fresh look at your lifestyle.

Davido Gbé Gbọ̀ngàn O2 Arena Síta Fún Eré Àìlópin Rẹ̀

202

Akọrin tàkasùfé ọmọ Nàìjíríà nì ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí David ti gbe gbọ̀ngàn tó gbajumọ̀ – O2 Arena ni Ìlú London síta látàrí ere orin rẹ ti yóò wáyé ni ọjọ kejidinlogbon, osu kínní, ọdún 2024. Lórí òpó ẹ̀rọ X ni wọ́n ti kéde rẹ̀.

Ni ọdún 2019, Davido jẹ akorin ẹlẹ́nikan àkọ́kọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè yìí tí yóò ta ogun ẹgbẹ̀run ààyè O2 Arena, fún eré to wa fi idi re mule pe o jẹ Olùdásílẹ̀ ati èèkàn ìtẹ̀síwájú orin takasufe-Afrobeats.

Àlá Davido kọjá pe a n ta Àrẹ́nà, wọn ti aan ni ìgbà mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ fún idije Grammys, Ó ti gba eléré ilẹ̀ Adúláwọ̀ to dara ju (“Unavailable”), ó tún gba ti ti agbaye- Best Global Song Performance (“Feel”),àti Best Global Album (“Timeless”). àti bẹbẹ lọ.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Comments are closed.

button