Iṣẹ́ ọ̀gbìn èso Kiwi jẹ ohun ọgbin ìpìlẹ̀ láti ìgbà ayé wa.
Èso yìí jẹ́ èso ti wa láti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà China, nígbà tí ọ di akoko kàn wọn mú Ọ̀gbìn èso yìí ló sì Orílẹ̀-èdè Zealand, titi won fi mú dè Orile-èdè Nàìjíríà nipasẹ káràkátà.
Ni ọdún 1920 ní won gbìn èso yìí sì Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣùgbọ́n latari ayi ìmọ̀ to lori rẹ ko gbilẹ si.
Èso yìí jẹ ohùn tí ọ mu ọ̀rọ̀ aje dàgbà, tó sì ni mu ètò ọ̀rọ̀ aje gbà, ti àwọn àgbẹ̀ sí n je eré.