Take a fresh look at your lifestyle.

Ṣẹ́nitọ̀ Láti Ìpínlẹ̀ Anambra Pin Àwọn Ohun Elo Irinṣẹ́ Tó Lé Ní Ẹgbẹrun Méjìlá.

174

Aṣojú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tó n sójú ìpínlẹ̀ Anambra, Ṣẹ́nitọ̀ Tony Nwoye ti ṣe ojúṣe rẹ nípa ṣíṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà 

Àwọn ohun èlò irinṣẹ́ to tó ẹgbẹ̀rún Méjìlá, ni àwọn ènìyàn jẹ ànfààní rẹ.

Àwọn tó jẹ Ànfààní náà ni won mu láti àwọn agbègbè gbogbo ki ànfààní náà bá lè kárí.

Àwọn ohun irinse bi masini ìransọ, masini ìlọ̀gi, ẹrọ amunawa, àpò ìrẹsì àti bẹẹ bẹẹ lọ.

Ṣẹ́nitọ̀ wa tun se ìlérí wí  pé òun yóò túnbò tẹṣiwájú láti ṣe àtìlẹ́yìn fún agbègbè òun, o ní lára àtìlẹ́yìn náà ni Bílíọ̀nù Merinlegbon Náírà ti ijoba àpapọ ní àwọn yóò fi se ìrànlọ́wọ́ fún àtúnse popona Otucha-Nzam-Ida sí Abuja.

Comments are closed.

button