Take a fresh look at your lifestyle.

Àgbẹ̀ Ẹlẹ́ja Àrọ̀ Fẹ́ Ìmúlò Ètò Ìṣúná ti Ọdún 2024

209

 

Àgbẹ̀ Ẹlẹ́ja Àrọ̀, àjọ Catfish Farmers Association of Nigeria (CAFAN) fẹ́ ìmúlò ètò Ìṣúná ti Ọdún 2024 to múyán lórí fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka náà.

Ààrẹ CAFAN, Ogbeni Sunday Onoja pé ipe yi ni ọjọ Ọjọ́bọ̀ ní ìlú Èkó.

Onoja rọ ilé iṣẹ́, lẹ́gbẹ́ lẹ́gbẹ́, lájọ lájọ, ẹ̀ka jẹ̀ka láti ri pe wọ́n se ìmúlò ètò ìṣúná fún ẹ̀ka náà ni ọ̀nà tó ydara kí ìtẹ̀síwájú leè wà.

“Ọ̀nà kan ni láti ṣe àgbékalẹ̀ ètò ìṣúná ọdún tuntun tó dára, ìmúlò ati wíwá sí ìmúsẹ rẹ̀ ló se pàtàkì jù.

” A ní ìgbàgbọ́ pé ọdún 2024 yóò dára ti a bá se àmúlò àwọn gbogbo eyto rere ìjọba daradyara,” Onoja sọ èyí

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button