Take a fresh look at your lifestyle.

Davido Pẹ̀lú Aya Rẹ̀ Ń Yọ̀ Sẹ̀sẹ̀ Nígbà Tí Wọ́n Sàfihàn Àwọn Ìbejì Tí Olódùmarè Fi Tawọ́n Lọ́rẹ

172

Davido se ìfiléde fán-án-rán fídíò èyí tí ó sàfihàn Òun, Aya rẹ̀ Chioma àti àwọn ìbejì tí Olódùmarè fi ta wọ́n lọ́rẹ níbi tí àwọn ọ̀tọ̀nkùlú ènìyàn ti dunnú pẹ̀lú wọn

 

David Adeleke tí gbogbo ayé mọ̀ sí Davido ni ó wà pẹ̀lú ìdílé rẹ̀ níbi tí gbajú-gbajà olórin náà ti se àfihàn fídíò Òun àti àpapọ̀ ìdílé rẹ̀

 

Akọrin náà padà sí ilé lẹ́yìn ìgbà tí ó ti seré káàkiri Orílẹ̀-èdè àgbáyé, Ó wá fí ìdùnnú rẹ han pẹlu dídarapọ̀ mọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀

 

Comments are closed.

button