Take a fresh look at your lifestyle.

Makinde Yan Fola Oyekunle Gẹ́gẹ́ Bíi Makinde Yan Folu Oyekunle Gẹ́gẹ́ Bíi Igbákejì Olórí Òṣìṣẹ́ Rẹ

220

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti fi ọwọ sí ìyànsípò Fola Oyekunle gẹ́gẹ́ bíi igbákejì olórí òṣìṣẹ́ rẹ̀.

Oyekunle náà ló jẹ́ ọkan lára àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Kẹsán sojú Ẹkùn Àríwá Ìbàdàn kínní (Ìbàdàn North 1), nibi tó ti jẹ́ Alága ìgbìmọ̀ ilé lórí ọ̀rọ̀ ọ̀dọ́ àti eré ìdárayá.

Bákan náà ni Oyekunle tún jẹ́ Alàkóso fún Àríwá Ìbàdàn to se kòkáárí igbimọ to rí sí ìyànsípò ẹlẹẹkeji Makinde gẹ́gẹ́ bíi Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lẹẹkeji.

Nígbà tó n ki í kú oríire fún iyansipo gẹgẹ bíi igbákejì olórí àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀, Gómìnà Makinde gba Oyekunle níyànjú láti ṣíṣe ni ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ yòókù láti mú kí àlàkalẹ̀ fún ìdàgbàsókè ọlọjọ pipẹ ti ọdún 2023 – 2027 àti ìdàgbàsókè Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lè wá sí imusẹ.

Abiola Olowe
Ìbàdàn

Comments are closed.

button