Adari ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Abbas Tajudeen ti ba ọlọ́jọ́ìbí Nyesom Wike yajo ọjọ́ ìbí re ni ẹni Mẹ́rìndínlọ́ọ̀gọ́ta loke ìpẹ̀.
Abbas ṣe àpèjúwe rẹ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí o ṣe fi okan tan nipa iṣẹ rẹ sí Orílẹ̀-èdè Nàìjíría.
Olubadamoran pataki fún ọ̀rọ̀ aféfé , Musa Abdullahi Krishi lọ sọ èyí di mímọ̀, wí pé Adarí ilé ìgbìmọ̀ sọ wí pé iṣẹ́ Wife n sọhun fún ni gbogbo ọ̀nà.
Ó ní ma le gbàgbé ni àwọn iṣẹ takuntakun ti wike gbé ṣe ni Ìpínlẹ̀ Cross River lákòókò rẹ gẹ́gẹ́ Gómìnà ni gbana.
Ó wà agbadura fún ìlọsíwájú àti àlàáfíà fún ọlọjọ ibi