Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa Dẹ̀kun Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Láti Ta Àbùkù Bá Orúkọ Àwọn Adájọ Ni Ìpínlẹ̀ Náà.

0 144

Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa ti dẹ́kun ẹgbẹ́ òṣèlú PDP láti má ṣe bú enu àbùkù Lu orúkọ àwọn adájọ ìpínlẹ̀ náà nitori eto ìdìbò to wáyé.

Nínú ọ̀rọ̀ àtẹ̀jáde kàn tí Akọ̀wé àgbà fún Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Abdullahi Sule sọ, Akọ̀wé fún ọ̀rọ̀ gbogbo, Ọ̀gbéni Peter Ahemba kọ tí o sì kà fún àwọn Oníròyìn ni ọ̀rọ̀ náà tí jáde.

Látàrí ìwọ́de to wáyé ni Lafia  ni láti ọwọ́ ẹgbẹ́ PDP lo mu àmọ̀ràn waye , látàrí bi  ilẹ ẹjó ṣe wí pé ni ẹgbẹ́ òṣèlú APC ló yege fún ìdìbò ìpínlẹ̀ náà.

Ó  ni kò ba da bi ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ba gbà ilẹ ẹjọ́ láti fi ẹdun ọkan wọn hàn

Ó  wa rọ àwọn òṣìṣẹ́ aláàbò láti rí wí pé kò sí enikéni tó farapa lákòókò ìwọ́de náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button