Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Fún Àwọn Alágbàṣe Ní Ọjọ́ Mẹ́rinla Láti Pàdà Sí Ẹnu Ìṣẹ́

0 293

Àwọn alágbàṣe ìṣẹ́ òpópó-ònà ní orílẹ̀-èdè Naìjírìà ní wọ́n tí fún ní ọjọ́ mẹrinla láti pàdà sí ẹnu iṣẹ́ tàbí kí wọ́n gbá iṣẹ́ náà pàdà.

Mínísítà fún iṣẹ́ ọnà, Sẹnetọ David Umahi ṣé agbekalẹ èyí nínú ìpàdé pẹ̀lú àwọn alágbàṣe tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè yìí àti àwọn tí ilẹ̀ òkèèrè ní Abuja, Olú-ìlú Naìjírìà.

Sẹnetọ Umahi fí kún pé àwọn alágbàṣe tí kó tíì parí iṣẹ́ wọ́n kó ní ní anfààní láti gbà òmíràn nínú àwọn iṣẹ́ àkànṣe túntún tí Ààrẹ fọwọsi láìpẹ́ yìí.

Mínísítà náà tún fi ìgbé tá pé àwọn oún èlò ayederu tí àwọn alágbàṣe wọnyí nlo kó bójú mú.

Seneto Umahi sọ fún àwọn alágbàṣe náà pé kò ní sí igbalaye láti máa lò ogún ọdún lórí iṣẹ́ kàn gẹ́gẹ́ bí tí at’ẹyin wá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button