Ó jú mílíọ̀nù mẹ́ta àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yóò ní anfààní láti kópa nínú ètò ìmọ-ẹrọ pàtàkì kàn tí ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú WEMA Bank Plc.

Ètò náà tí wọ́n pé ní ‘Skillinovation’ yóò pèsè àwọn anfààní pẹ̀lú ìmọ ọgbọn tó nilo ṣaṣeyọri nínú ètò-ọrọ àjé àgbáyé.

Èyí wá láti ṣé àtìlẹ́yìn imọ-ẹrọ àtí àlàyé tí yóò wà ní arọwọto eto-ọrọ àjé àti ìlọsíwájú ìdàgbàsókè àwùjọ Nàìjíríà.

Leave a Reply