Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn Fún Ìlera Yan Ààrẹ Tuntun.

0 191

Ẹgbẹ́ Àwọn Oníròyìn fún ìlera (ANHEJ) ti Yan Ààrẹ Tuntun fún ẹgbẹ́ náà, Ògbéni Joseph kadiri, to jẹ oníròyìn fún ilẹ̀ iṣé tẹlifísàn ITV gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ fún ẹgbẹ́ náà.

Nigba tí ó ń dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ lórúko gbogbo àwọn Olóyè tó kún Kadiri ní òun dúpẹ́ fún yiyan ti wọn Yan òun sí ipò gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ

Ọdún méjì gbáko ní Kadiri àti àwọn ìgbìmọ̀ rẹ yóò fi  ṣà koso Ẹgbẹ́ náà.

Ó tún dúpẹ́ lọ́wọ́ Ààrẹ to ṣẹṣẹ Kúrò lórí ipò àti àwọn ìgbìmọ̀ rẹ fún iṣé takuntakun wọn

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button