Àjọ ìlera Làgbáyé (WHO) tí Gbóríyìn fún ìjọba ìpínlẹ̀ Kano fún àpẹrẹ réré tó fi hàn àti àtìlẹ́yìn rẹ lórí ọ̀rọ̀ ìlera, nípa di dèna àìsàn to n ba imú po.
Aṣojú àjọ WHO ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Walter Kazad sọ wí pé ìpínlẹ̀ náà ti fí àpẹrẹ réré hàn nípa ìlera lórí ilu náà.
Ó sọ èyí nígbà ẹgbẹ́ Global Fund ṣe ìbẹ̀wò sí Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Abba Yusuf ni ilé ìjọba ni ọjọ́rú.
O wà rọ gbogbo awọn ìpínlẹ̀ tó kún láti wo àwòkọ́ṣe ìpínlẹ̀ náà fún ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Gómìnà Yusuf sọ fún ilẹ iṣé Global Fund wí pé ìjọba ìpínlẹ̀ òun yóò tẹ̀sìwájú láti rí wí ìpínlẹ̀ náà wà nínú àláfíà pípé