Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra rọ àwọn ọ̀dọ́ láti ní iṣẹ́ ọwọ́

0 202

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Gúsù ilà oòrùn Nàìjíríà, Ọj̀ọ̀gbọ́n Chukwuma Charles Soludo, ti gba àwọn ọ̀dọ́ nímọ̀ràn láti ní iṣẹ́ ọwọ́ tó ṣe pàtàkì láti le kópa bóṣe tọ́ àti  bóṣe yẹ ní ọjọ́ iwájú.

Gómìnà Soludo gba awọn ọdọ ti papa iṣere ilu Awka nimọran lasiko Idahun Irin Fun Igbe-Aye to dara, ti oṣu kẹsan an, ti igbimọ idagbasoke ere idaraya ni ipinlẹ ṣagbatẹru rẹ.

Nigba ti o n sọrọ lẹyin Irin naa, Gomina Soludo sọ pe ọdọ to ni ile, agbalagba, ati awọn agbalagba oṣiṣẹ, ni  Anambra pelu ni Naijiria, ṣe pataki fun ilọsiwaju orilẹ-ede.

Nigba ti o wa n tẹnumọ pataki ajumọṣepọ ati iṣọkan fun idagbasoke, Gomina Soludo  tun wa fi to wọn leti pe ọmọ ẹgbẹ Agunbanirọ to to ọgọrun un ti kopa ninu Eto Ọdọ kan Iṣẹ Ọwọ Meji”,  ti o si fikun un pe titi ipari oṣu yii, olukopa to ti ṣaṣeyege, to ju ọọdunrun lọ yoo ni anfaaani ninu fifunni lowo naa ati ti wọn yoo si di ẹni to le da duro funra rẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button