Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima, sọ pé Ààrẹ Bola Tinubu tí ṣetán látí mú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dé ilẹ̀ ìlérí.
Ó ṣé ìkéde náà ní ọjọ́ Ajé, nígbà tó ń ṣí ìpàdé ètò ilanilọyẹ kàn fún àwọn olùrànlọwọ olóṣèlú lórí ìlànà ìṣàkóso àti ètò iṣéjọba ìlú.

Ìpàdé náà, èyítí o wáyé ní Ilé-iṣẹ́ Ológun tí Nàìjíríà Abuja, èyí tí Ilé-ìgbìmọ̀ ìjọba àpapọ̀ pẹ̀lú Direct Knowledge Consult Ltd.
Ilanilọyẹ náà, eyiti yóò wáyé ní ìpele méjì, á bẹ̀rẹ̀ láti 22nd Oṣù Kẹ̀sán, 2023.
Nígbà tó ń bá àwọn olukopa sọrọ, èyítí ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọ́n jẹ́ àwọn olùrànlọwọ olóṣèlú àti àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, Ìgbákejì Ààrẹ rọ̀ wọ́n látí ríi dájú pé wọ́n fi ikunju òṣuwọn hàn lẹ́nú iṣẹ́.
Leave a Reply