Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger Gbà Egberun Kan Àwọn Òṣìṣẹ́ Elétò Ìlera.

0 225

Gómìnà ìpínlẹ̀ Niger sọ wí pé lára ìlérí òun láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ìlera, òun yóò gbà àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ òṣìṣẹ́ elétò ìlera, láti mú ìfàsẹ́yìn to n ba ètò ìlera kúrò.

Gómìnà Umaru Bago ti ìpínlẹ̀ Niger ló sọ èyí di mímọ̀ ni ọjọ́ ẹtì lákọ̀kọ̀ọ́ to n Pin àwọn ohun èlò isé sí àwọn ìjọba ìbílẹ̀ márùn-únlẹlogun to wà ní ìpínlẹ̀ náà.

Bago sọ wí pé àwọn Dọ́kítà, nọ̀ọ́sì, àti àwọn òṣìṣẹ́ elétò ìlera ṣe pàtàkì jù lọ ní láwùjọ.

Ó ní ìjọba tí bu wọ lu owó láti ṣe àwọn àtúnṣe sí àwọn ilé ìwòsàn káàkiri ni ìpínlẹ̀ náà.

Dọ́kítà Gerida Birukila tó jẹ́ òṣìṣẹ́ elétò ìlera fún àgbáyé ni ìpínlẹ̀ Kaduna  ni dupẹ púpọ̀ fún àkìntíyàn ati àtìlẹ́yìn ìjọba fún ìdàgbàsókè lórí ètò ìlera.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button