Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Tinubu fí ìkíni o kú Órire ranṣẹ sí igbákejì rẹ Kashim Shettima fún ayẹyẹ ojó ìbí tí ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta to wáyé ni ọjọ́ Kejì oṣù kẹsán ọdún 2023.
Nígbà tí ó n ba ẹbí, ará, ọ̀rẹ́ yọ̀, Ààrẹ dupẹ lọwọ ọlọrun lórí ìgbé ayé Gómìnà tẹlé rí fún ìpínlẹ̀ Borno
Ó wà gbàdúrà fún, ìmọ̀, ọgbọ́n àti àlàáfíà tó péye
Ààrẹ fi Ànfààní náà dupẹ lọwọ igbákejì rẹ fún òtítọ àti ifaraji rẹ fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Ó ní àti fún ìgboyà tó fi ṣàkóso ìpínlẹ̀ Borno fún ọdún mẹjọ gbáko èyí tí iṣẹ ọwọ rẹ sì n fohùn titi di igba yii
Leave a Reply