Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Oluremi Tinubu tí gbé oríyìn fún àwọn aráàlú tí wọ́n pàdánù ẹ̀mí wọ́n nínú ìkọlù bọ́ǹbù tí Ilé-iṣẹ́ Àjọ Àgbáyé ‘United Nations’ ní ìlú Abuja ní ọjọ́ kẹrindinlọgbọn Oṣù Kẹjọ Ọdún 2011.

Nígbà tó n sọ̀rọ̀ nílu Abuja lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun, níbí ayẹyẹ fífi aṣeyẹ lélẹ̀ fún àwọn tó pàdánù ẹ̀mí wọ́n nínú ìṣẹ̀lẹ̀ náà, Arábìnrin Tinubu pé fún ipá tó lágbára lórí àwọn àfi-ẹ̀mí-ṣófó náà látí dáàbòbo àwùjọ.
Látí ṣé àṣeyọrí èyí, Ìyááfín náà sọ pé àwùjọ Àgbáyé gbọ́dọ̀ dójú kọ́ ètò àlàáfíà, Ìjíròrò àti igbogunti àwọn ìwà ikorira ẹ̀yà tàbí èdè.

Àjọ Àgbáyé náà dárapọ̀ mọ́ Àyà Ààrẹ lábẹ́ Àkọwé Gbogbogbò tí UN lórí Ilé-iṣẹ́ igbogunti àwọn àfi-ẹ̀mí-ṣófó, Vladimir Voronkov níbí ìrántí náà.
Leave a Reply