Ẹkún omí: Orílẹ̀-èdè Cameroon Yóò Ṣí Lagdo Dam – Wọ́n Ṣé Ìtáníji Fún Ilé-iṣẹ́ NEMA
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Ilé-iṣẹ́ ilẹ̀ òkèèrè tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (Ẹ̀kà Ìlà-oòrùn àtí Àárín gbùngbùn Áfríkà) tí sọ fún Ilé-iṣẹ́ pajawiri tí Orílẹ̀-èdè (NEMA) pé àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba Cameroon tí pinnu láti ṣí àwọn ibodè ikùn Omí tí Lagdo Dam sí odò Benue nítorí Òjò arooda.
Èyí jẹ́ àlàyé nínú lẹta kàn tí Umar Salisu Fọwọ́sí, Olùdarí Ilé-iṣẹ́ tì Áfíríkà fún Àkọwé àgbà ní ọjọ́ kọ́kànlélogun, Oṣù kẹ́jọ, ọdún 2023.

Olùdarí náà sọ pé Ilé-iṣẹ́ náà gbá ọrọ̀ àkọsílẹ náà látí ọdọ Ìgbìmọ̀ gíga tí Cameroon lórí àwọn ètò láti “Ṣí àwọn ẹnubodè ikùn Omí tí Lagdo Dam lórí Odò Benue ní àìpẹ.”
Leave a Reply