Adari ile iṣé tí o n mójú tó ẹ̀rọ ìgbàlódé ti ṣe ìlérí láti ṣe àtìlẹ́yìn àti ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọ Obinrin ati awọn àgbà Obìnrin ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Kashifu Inuwa sọ èyí di mímọ̀ ni ìlú Abuja nígbà tí o n sọ̀rọ̀ níbi ìpàdé pẹ̀lú àwọn Akẹ́gbẹ́ wọn, pẹ̀lú Àkọlé wí pé Dídẹ̀na ìwà ìbàjẹ́ sí àwọn Obìnrin, èyí tí ilé iṣé ìjọba fún ọ̀rọ̀ àwọn obinrin gbé kálẹ̀.
Ọ̀gá àgbà fún Ilé iṣé NITDA sọ wí pé ọnà àbayọ láti dènà ìwà ìbàjẹ́ sí àwọn Obìnrin ni ki ànfààní fún wọn lati sọ̀rọ̀ lórí ẹrọ ayélujára pẹ̀lú
Kókó ìpàdé ọjọ́ kan náà ni láti fọwọ́sowọ́pọ̀ fún àtìlẹ́yìn fún àwọn Obìnrin ki ìwà ìbàjẹ́ sí wọn bá le dáwọ́ dúró.
Leave a Reply