Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ Kéde Àìsàn Ìbà Gẹ́gẹ́ Bi Ohun Tó Léwu Jùlọ: Àwọn Aṣòfin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà 

0 181

Alága ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lórí ọ̀rọ̀ àrùn kògbọ́ògùn, ikọ́ ife àti àìsàn ibà, Amobi Ogah ti rọ ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti kéde àìsàn ìbà gẹ́gẹ́ bí èyí tí o léwu julọ ti ó sì n ṣe iku pá ènìyàn.

Ogah ti o sójú Isuiwuato/Umunneochi láti ìpínlẹ̀ Abia, lo sọ èyí ni ìlú Abuja, ó ní bí a bá wo bi arun iba se ń kọlu Àwọn ènìyàn ó jẹ́ èyí tí o léwu púpọ̀ tí o sí n pa àwọn ènìyàn ní kíákíá.

Ó  ní àwọn ìjọba nílò iṣé nlá lori àìsàn náà láti lè rí wí pé wọn Dẹkun rẹ là wú jọ

Ó ní kí ìjọba àpapọ̀ àti àwọn tọ́rọ̀ kan ri wí pé wọ́n ṣe atilẹyin fún àwọn òṣìṣẹ́ ìlera láti rí wí pé ọ̀rọ̀ àìsàn ibà di ohun ìgbàgbé ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ayẹyẹ ọjọ́ Àìsàn Ibà lágbayé wa n wáyé ni ogunjọ́ ninu osù kẹjọ, Àkọlé: tí ọdún yìí ni Bí bá àìsàn to n ṣe ikú pani já.

Ọ̀rọ̀ yìí wáyé láti lè jẹ kí àwọn ènìyàn mọ ìjàmbá ti ó wa nínú àìsàn ìbà àti láti Dẹkun rẹ ní gbogbo ọnà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button