Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sen. Kashim Shettima tí ṣé itẹwọgbà bílíọ̀nù kàn lè díẹ̀ Náírà “N1.2 billion” owó ilé-iṣẹ́ Google èyí tí pèsè fún ìjọba Ààrẹ Tinubu fún ìṣàkóso ètò ìsẹ́ mílíọ̀nù kàn fún àwọn ọdọ.
Ìgbákejì Ààrẹ sọ ní Ọjọ́ Ìṣẹgun nígbàtí o gbà díẹ̀ nínú àwọn aláṣẹ tí Google – ilé-iṣẹ́ imọ-ẹrọ àgbáyé ní ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abuja.
Leave a Reply