Take a fresh look at your lifestyle.

Kó Tí Sí Ètò Fún Ogún Pẹ̀lú Niger Republic – Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin

0 413

Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ pé àwọn kó tíì gba àbá ogún kánkan látí ọdọ Ààrẹ Bola Tinubu látí bá Niger Republic jagun látàrí ìfipágbàjọba ní orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ àgbègbè rẹ̀.

Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin, Alàgbà Godswill Akpabio ṣé ìdánilójú ní ọjọ́ àbámẹ́ta nínú ìpàdé ìgbìmọ̀ náà làkókò tí wọ́n fí ọrọ wá àwọn tí Ààrẹ yán gẹ́gẹ́ bí Mínísítà.

Sẹnetọ Akpabio ṣàlàyé pé Ààrẹ Tinubu tó tún jẹ́ Alága ECOWAS nìkan ní o béèrè fún Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Orílẹ-èdè náà látí ṣé àtìlẹ́yìn fú ìpinnu ECOWAS.

Lẹyìn èyí, Sẹnetọ rọ́ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ECOWAS látí bu ẹnu lú igbajọba náà pátápátá, kí wọ́n wà ojútùú sí aawọ náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button