Take a fresh look at your lifestyle.

Niger: Aṣoju ECOWAS ko le ri adari ologun

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 442

Aṣojú láti Gúsù iwọ̀ oòrùn Adúláwọ̀ ECOWAS kò le rí adari ológun tí ó kéde ìmúkúrò àdéhùn ológun tó wà láàrin Niamey àti Paris.

Aṣojú láti Gúsù iwọ̀ oòrùn Adúláwọ̀ agbegbe ECOWAS gunlẹ sí orilẹ-edeAṣoju Niger ní irọlẹ Ọjọbọ, fun ijumọsọrọ pẹlu adari ologun, Ajagun Abdourahmane Tiani.

Aṣoju naa ti aarẹ Naijiria tẹlẹ ri Abdulsalami Abubakar, ṣadari yẹ ki o gbe ibeere awọn adari ECOWAS siwaju wọn.

Awọn Aṣoju pataki naa pada ni wakati diẹ lẹyin ti wọn debẹ,lai ri adari ologun tabi aarẹ ti wọn le kuro lori oye, Mohamed Bazoum.

Aarẹ Naijiria Bọla Tinubu, ti o jẹ alaga Ajọ naa, wa rọ awọn asoju naa lati ṣe nkan kinkan ti o ba gba lati ri pe wọn yanju rogbodiyan orilẹ-ede Niger naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button