Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Àwọn Aṣojú Bẹ̀rẹ̀ Ìwádìí Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ìjọba Lórí Gbígbà Òṣìṣẹ́

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 356

Ìgbìmọ̀ ìdá kọ́nkọ̀ àwọn Aṣojú tí Ilé àwọn Aṣojú ní látí ṣé ìwádìí àwọn ilé-iṣẹ́ Ìjọba àpapọ̀, Ẹ̀kà àtí àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba kereje (MDAs) àtí àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga lórí àwọn àìṣé déédé ìgbànísíṣẹ́ láìní ìṣàkóso tó tọ́, ìgbànísíṣẹ́ lọ́nà erú, àti Aiṣedede lórí ‘Intergrated payroll and personnel information system IPPIS.

Ni ìbámu pẹ̀lú àwọn ìwádìí náà, ìgbìmọ̀ náà tí pàṣẹ fún Ọfisi ètò Ìṣúná tí ìjọba àpapọ̀, Olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ àtí àjọ tó ń gba’ni síṣẹ́ ìjọba àpapọ̀, látí wá síwájú rẹ̀ láì kùnà.

Alága tí Ìgbìmọ̀ náà, Yusuf Gagdi, kàn èyí nípa níbí ìjókó ìwádìí tó ń tẹ̀síwájú ní Abuja ní Ọjọ́rú.

Ó sọ pé “ìgbìmọ̀ náà kò ní fàyè gba àwọn olórí ilé iṣẹ́ ìjọba tí kó ní yọjú síbi Ijoko wá sọ́ t’ẹnu ẹ́.”

Alága náà tún ṣé ìdánilójú pé ìgbìmọ̀ náà kó ní fàyè gbá ọmọ ẹgbẹ́ kọ̀ọ̀kàn láti dójú sọ́ ẹnikẹni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button