Take a fresh look at your lifestyle.

Òṣèré Tíátà Kan Dì Akọ̀wé Ayẹyẹ Ẹgbẹ́ Ìyàwó Àwọn Sẹ́nétọ̀

0 248

 

Gbajúmò òsèrébirìn kan, Regina Daniels ni wọ́n ti yàn gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé ayẹyẹ ẹgbẹ́ Ìyàwó àwọn Seneto ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

 

Ìyáàfin Regina kéde ìyànsípò rẹ̀ ní orí òpó instagramu ní ọjọ́ Ọjọ́rú, oṣù keje ọdún 2023. Ó fi inú dídùn rẹ̀ hàn fún ipò náà àti èròngbà rẹ̀ fún Nàìjíríà tó ga.

Ó sọ síwájú, ó kọ pé ” Àná ni ìpàdé ìgbaniwọlé ti Ẹlẹ́kewàá Ẹgbẹ́ aya àwọn Sẹ́nétọ̀ ti Nàìjíríà wáyé tí iya wọn Ọlọ́lá rẹ̀, Ìyáàfin Màmá Ekaette Akpabio,, aya ààrẹ àwọn Sẹ́nétọ̀ orílẹ̀-èdè gbà wọ́n lálejò “.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button