Akọrin omo Nàìjíríà , Damini Ogulu, ti wọ́n mọ̀ sí Burna Boy,ti sọ̀rọ̀ nípa orúkọ tí wọn fún nínú eré orin – “Olóngbò tuntun “- new cat.
Burna boy so pé òun rí inagijẹ náà bí eni to ṣẹṣẹ bẹrẹ orin ati pé òun rí bí anfààní nla fùn oun.
Ninu ìfòròwánilénuwò kan ti won se fún Davido, o sọ pé òun àti Wizkid ni oludasile orin ‘Afrobeat’ . Ati wí pé àwọn yòókù bii Burna Boy, Rema, Asake, abbl, ni ‘new cats’, wọn ti gbe ere orin naa lo sì ipele to kan.
Bí Burna boy se sọ, ìnagijẹ tuntun náà ni òun rí bí ẹni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ eré orin àti pé ó fún òun ní anfààní tó pọ̀ láti ṣe bẹbẹ sí àti ẹ̀mí gígùn.
.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply