Take a fresh look at your lifestyle.

Yíyọ Owó-Ìrànwọ́ Orí Èpò Kúrò: Ijọba Nàìjíríà Ṣé ìdánilójú Ètò Ìrọrùn

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 320

Alága, Àjọ ètò ìrọrùn lórí yíyọ ìrànwọ́ orí èpò kúrò “Palliative Committee on Subsidy Removal” àtí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kebbi, Dókítà Nasir Idris, tí fí dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lójú pé àwọn tí bẹ̀rẹ̀ ìgbìyànjú lójúnà látí ṣé ìdẹ́kun lórí ipá tí yíyọ owó náà kúrò.

Gómìnà náà ṣé ìdánilójú náà nígbà tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ rẹ̀ ṣé ìpàdé ní Abuja ní ọjọ́ Àbámẹ́ta.

Èyí ló jẹ́yọ́ nínú ọrọ̀ ágbẹ́nùsọ Gómìnà Ahmed Idris.

Àwọn tí wọ́n wà níbí ìpàdé náà ní Gómìnà Bala Mohammed tí Bauchi, Charles Soludo tí Anambra, Uba Sani tí Kaduna àti Hyacinth Alia tí Benue, àtí àwọn aṣojú Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ atí Ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ́ ọmọnìyàn.

Alága náà sọ́ pé ẹrín yóò gbẹ́nú àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí láìpẹ́, nítorí pé ìgbìmọ̀ náà ń pétó òun tó dára látí ṣé ìrànlọ́wọ́ àtí ìrọrùn fún àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button