Ilé-iṣẹ́ ìfọ́pó orílẹ̀-èdè Nàìjíríà “Nigeria National Petroleum Company Limited NNPCL” sọ pé o tí ṣé tàn látí gbé gáàsì kọjá lọ́ sí ìwọ̀ òòrùn Áfríkà títí dé Yúróòpù.
Olùdarí àtí Aláṣẹ tí ẹgbẹ́ NNPC, Mele Kolo Kyari sọ èyí nígbà tó ń bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ pàtàkì kàn lórí “Redefining Nigeria’s Energy Landscape for a Sustainable Energy future” ní ọdún yìí níbí tí “Oil and Gas Energy Week” nlọ lọwọ ni Abuja, Nàìjíríà.
Leave a Reply