Ààrẹ Bola Tinubu ti rọ àjọ National Population Commission NPC láti tẹ̀ síwájú pẹ̀lú ìmúrasílẹ̀ fún kíkà ìyè àwọn ènìyàn orílẹ̀-èdè tí wọ́n sun síwájú.
Alága tí NPC, Nasir Kwarra sọ fún àwọn oníròyìn Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ lẹyìn tó ṣé aṣojú ìgbìmọ̀ kàn lọ́ sí Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ, Abuja, látí pàdé pẹ̀lú Ààrẹ.
Kwarra sọ pé àwọn tí fí ìgbáradì wọ́n hàn Ààrẹ, yóò sì kéde ìgbà tí ikaniyan náà yóò wáyé.
Alága NPC, tó sọ pé ìgbálédíẹ̀ bílíọ̀nù náírà N200B ní àwọn yóò ló fún ikaniyan náà, Ó wà ṣé ikìlọ̀ pé tí àbá rá àkókò laré, o ṣeéṣe kó jù bẹ́ẹ́ lọ́.
Leave a Reply