Take a fresh look at your lifestyle.

World Refugee Day: Nàìjíríà Pé Fún Ìgbìyànjú Látí Ṣé Àtúnṣe Àtí Ààbò

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 179

Ọjọ́ àwọn àlásálà lágbayé tí 2023 parí pẹ̀lú ìpe àwọn alẹ́nu-lọ̀rọ̀ látí wá ọ̀nà àbáyọ́ sí ìpenija tó ń kojú àwọn àlásálà lágbayé.

Kọmisọna àgbà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún Ìgbìmọ̀ àwọn àlásálà àti àwọn ènìyàn tí a f’ipa ṣí nípò, Imaan Suleiman-Ibrahim sọ pé ọ tí dandan kí a wó gbogbo òun ìdènà tó ń ṣé ìdíwọ́ fún àwọn wọ̀nyí.

Àjọ Àgbáyé àti Alákóso Ọmọnìyàn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọ̀gbẹ́ni Matthias Schmale sọ pé àwọn wọnyí nílò ánu, àtìlẹ́yìn àti ìsọkan l’aini ààlà tàbí tari wọ́n pàdà sẹyìn.


Ó fí hàn pé Naijiria tí gbàléjò àwọn tí wọ́n ṣá àsálà fún ẹ̀mí wọ́n tó fẹ́rẹ̀ tó ọkẹ́ márùn 100,000 àti àwọn tó ń fẹ́ ààbò láti àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́rinlèlọ́gbọ́n 34, tí àwọn tó jù jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Cameron.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button