Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn tó ní ṣe pè fún ọgbọọgba fún takọ tabo akọ̀ròyìn, ìjọba tó dára

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 205

Àwọn tó ní ṣe nínú iṣẹ́ akọ̀ròyìn ti rọ àwọn akọ̀ròyìn lórí pàtàkì láti túnbọ̀ ṣàgbélárugẹ ọgbọọgba fún takọ tabo akọ̀ròyìn ati ìjọba tó dára fún Naijiria.

Wọ́n pe ìpè yìí níbi àjọṣepọ̀ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́jọ́ méjì kan láàrin ilé-iṣẹ́ ìjọba fún ètò ẹ̀kọ́ àti ìgbìmọ̀ Nàìjíríà lápapọ̀ fún UNESCO, tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ : Ipa iṣẹ́ akọ̀ròyìn tó láàbò àti ọgbọọgba fún takọ tabo àti ìjọba tó dára nínú ìjọba tiwantiwa ní Nàìjíríà.

Idanilẹkọọ ọlọjọ meji yii yoo da lori bi awọn akọroyin yoo ṣe tunbọ mu ayipada to dara ba takọ tabo akọ̀ròyìn ati ìjọba tó dára fún Naijiria.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button