Take a fresh look at your lifestyle.

“Kòsí ìbẹ̀rù lórí ilé-ìgbìmọ̀,” – Adarí ilé ìgbìmọ̀ tẹ́lẹ̀ rí

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 238

Adarí ilé ìgbìmọ̀ tẹ́lẹ̀ rí tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò, Snet Ovie Omo-Agege, ti sọ pé kò séwu lórí ilé-ìgbìmọ̀ pẹ̀lú bí Sẹ́ntọ̀ Godswill Akpabio ṣe jẹ́ Adarí ilé ìgbìmọ̀ kẹwàá tuntun.

Ó sọ èyí nínú àlàyé oríire tí ọ̀gá àgbà Akọ̀wé rẹ̀, Ọ̀gbẹ́ni Sunny Areh, fi síta tí ó sì pín fún àwọn akọ̀ròyìn,ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun,ní Asaba, olú ìlú ìpínlẹ̀ Delta.

Lásìkò saa meji Omo-Agege, (2015- 2019; 2019- 2023) gẹge bi igbakeji Adarí ilé ìgbìmọ̀, tí ó ṣoju Aringbungbun agbegbe  Delta.

Ó ní oun ni igboya ninu “ iṣeto Akpabio”.

Omo-Agege, ti o jẹ oludije ipo gómìnà ìpínlẹ̀ Delta labẹ asia ẹgbẹ́ oṣelu APC ní ọjọ́ kejidin-logun,oṣu Ẹrèná, ọdún 2023, tún ṣajọyọ pẹlu Sẹnetọ Jubrin Barau, ẹni ti o jawe olubori fun igbakeji adarí ilé ìgbìmọ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button