Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ Nigeria Labour Congress NLC, tí ṣọ̀fọ̀ ikú Olóyè Raymond Dokpesi, olùdásílẹ̀ tẹlifíṣọ̀n olómìnira àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, The African Independent Television AIT.
Nínú atẹjade kàn tí Ààrẹ NLC, Joe Ajaero fọ́wọ́sí, NLC tí ṣàpèjúwe Olóyè Dokpesi gẹ́gẹ́ bí ọmọluabi, ololufẹ àti aṣojú àṣà ilẹ̀ Áfíríkà àtí pàápàá ọ̀rẹ́ àwa òṣìṣẹ́.
Tún kà nípa:Àyájọ́ òṣìṣẹ́: Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ pè fún ètò ìrọ̀rùn fún àwọn òṣìṣẹ́
O ní bí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣé ń dáró ikú Dokpesi, NLC náà ń dáro pẹ̀lú ẹbí, ọrẹ àti ojúlùmọ́.
Leave a Reply