Igbákejì ààrẹ Nàìjíríà tuntun , Kashim Shettima bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun,tí ó sì ń fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé Bọla Tinubu yóò pèsè ìṣèjọba tó dára ní orílẹ̀-èdè.
Wọ́n búra fún Shettima gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ ní ọjọ́ Ajé,níbi ìbúra ààrẹTnubu, tí ó dije tí ó sì wọlé fún ìbò ọjọ́ kejìdín-lọ́gbọ̀n,oṣù Erèlé, 2023 ní Nàìjíríà.
O ba awọn oniroyin sọrọ ní kété tí o wọ ọfiisi rẹ ní abala igbakeji aarẹ ni Villa,ní Abuja.
Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ lori èròńgbà rẹ̀ fún Nàìjíríà, Shettima sọ pé ààrẹ Tinubu yóò ṣiwájú tí òun yóò sì gbe nígbùnwọ́ láti ṣe oun tí ó wu awọn ọmọ Nàìjíríà.
Leave a Reply