Take a fresh look at your lifestyle.

ÌBÚRA ÀÀRẸ TUNTUN: ÀWÒRÁN

0 193
Ètò ìbúra fún ààrẹ tuntun Ahmed Bola Tinubu (Jagaba) àti ìgbákejì rẹ̀ Kashim Shettima ti bẹ̀rẹ̀ ní Eagles Square tó wà nílùú Abuja

 

Àwọn ènìyàn pàtàkì ti wà níkàlẹ́, Abike Dabiri,Aliko Dangote, Omowe Akinwumi Adesina, Gómìnà àná fún ìpínlẹ́ Ogun, Gbenga Daniel, àwọn lọ́ba-lọ́ba

 

 

 

 

George Ọláyinká Akíntọ́lá

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button