Take a fresh look at your lifestyle.

Lai Mohammed Dágbéré Gẹ́gẹ́ Bí Mínísítà Tó Ló Sáà Tó Pọ̀jù

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 313

Mínísítà fún ètò Ìròyìn àti Àṣà tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Alhaji Lai Mohammed fí ìtàn balẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún Ìròyìn àti Àṣà tó ló sáà tó gúnjùlọ́ ní Orílẹ̀-èdè yìí.

O ṣé àpèjúwe àkókò ọdún mẹ́jọ̀ rẹ̀ bíi ìpenija síbẹ̀síbẹ̀ só èsó réré àtí òun manigbagb.

Mínísítà náà sọ èyí níbí àpéjọ ìdágbéré tí a ṣètò fún ní ilé iṣẹ́ ìjọba Ètò Ìròyìn àti Àṣà (Federal Ministry of Information and Culture) ní ọjọ́ Ẹtì ní Abuja.

Alhaji Mohammed tún sọ pé àwọn ilé-iṣẹ́ àtí òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ ìjọba náà gbìyànjú gidigidi nínú ìṣàkóso naa lórí òkìkí àti ìgbéga àṣà àwọn ènìyàn àti ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nípasẹ̀ ètò àlàyé fún gbogbo aráàlú tó mú ìrọrùn bá àwọn aráàlú bákannáà ní àgbáyé.

Tún kà nípa:Mínísítà Fún Ìrìn-àjò Ṣe Ìdágbére Fún Àwọn Mínísítà Tọ́kù.

Àpéjọ yìí jẹ́ òpin sáà èyítí o bẹ̀rẹ ní ọjọ́ kọkànlá, Oṣù kọkànlá, ọdún 2015 nígbàtí Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣé ìbura fun Mínísítà náà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button