Take a fresh look at your lifestyle.

Àyàjọ́ Àwọn Ọmọdé: Ààrẹ Nàìjíríà Pé Fún Ẹkọ Tó Yé Kóró

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 399

Ààrẹ Muhammadu Buhari ti rọ̀ àwọn Òbí àti àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pé kí wọ́n dì mọ́ àwọn òtítọ́ ìgbàanì ti ìwà tó tọ́, òtítọ́, ìmọ̀ àti iṣẹ́ àṣekára láìka àwọn àkókò yí pa dà, ó sọ pé àwọn àmì wọnyí ní yóò máa jẹ́ òpó àyànmọ́ wọ́n.

“Ni ọjọ́ pàtàkì yìí, a dúpẹ púpọ lọwọ́ Ọlọ́run fún ayé mìíràn láti ṣé ayẹyẹ àwọn ọmọ wà, ní Oṣù Kàrún ọjọ́ kẹtadinlọgbọn 27th, ọdún 2023. Gbogbo Ọjọ́ Awọn ọmọde ń rán wà létí ọjọ́ iwájú, àtí àwọn ifarada àti àwọn òun èlò ilé tó yẹ̀ látí ọdọ àwọn òbí, alágbàtọ, àwọn olùkọ́, àwọn Olùdarí àtí Ìjọba látí dáàbòbo àwọn ògo wẹ̀rẹ̀ wà.

Ààrẹ Buhari gba àwọn òbí níyànjú pé kí wọ́n máa bá àwọn ọmọ wọn lò pẹ̀lú ọ̀wọ̀, kí wọ́n sì máa gbájú mọ́ ìbáwí.

“A kì àwọn ọmọ wà kú oríire ayẹyẹ, ki Ọlọrun bùkún àwọn ọmọ wà,” o ṣé ajọyọ náà pẹ̀lú áwọn òbí, àwọn ọmọdé àti àwọn alágbàtọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button