Àjọ tó n rí sì ètò ìlera tí Ìpínlẹ̀ Kaduna, (Kaduna State Contributory Health Management Authority KADCHMA) tí rọ́ àwọn àgbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ náà látí gbá ètò iṣeduro ìlera tó n lọ́ lọ́wọ́ láàyè fún àlàfíà wọ́n.
Olórí, tí Àwọn iṣẹ́, Dókítà Juliana Dauda, ṣé ìpe náà làkókò ṣé ètò ìpolongo àtí ètò ìfitónilétí iṣoogun ní agbègbè Tomato Jos Farm Settlement, Kaigimi, Ìjọba Ìbílẹ̀ Igabi ní ọjọ́ Ẹtì.
Dauda sọ pé o ṣé pàtàkì fún àwọn Àgbẹ̀ látí dárapọ̀ mọ́ ọ̀gọ̀ọ́rọ̀ àwọn mìíràn lórí ètò iṣeduro ìlera látí ṣé adinku ìyè òwò ìtọjú àrà wọ́n.
Tún kà nípa:Àjọ Athletics Federation Of Nigeria Fẹ́ Tún Ètò Eré Ìdárayá Se Ní Ìpínlẹ̀ Kaduna
O sọ pé làkókò ètò ìfitónilétí náà, kó dín ní ẹgbẹ̀rún méjì àwọn olùgbé tí àgbègbè náà tó jẹ́ ànfààní ètò ìlera ọfẹ náà.
Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn ṣé sọ, KADCHMA fún àwọn ènìyàn ní ìwòsàn ọfẹ lásìkò ètò náà. Àwọn òṣìṣẹ́ ìlera àti àwọn mìíràn wà ní sẹpẹ láti ṣé ìrànwọ́ fún àwọn olùgbé àgbègbè náà lórí ìlera wọ́n.
Wọ́n ṣé àwọn àyẹ̀wò pàtàkì bíi, ifunpa, ìpèsè oògùn àtí bẹẹbẹ lọ́.
Leave a Reply