Take a fresh look at your lifestyle.

Ògùn Àti Àwọn Òṣìṣẹ́ Kò Tó Ní Ilé Ìwòsàn Orílẹ̀-èdè Sudan

0 303

 

Òṣìṣẹ́ ètò ìlera ti bẹ̀rẹ̀ sí ní se àròyé àìtó òṣìṣẹ́ àti ohun èlò bí ògùn ní ilé ìwòsàn Al-Now tó kalẹ̀ sí Omdurman, orílẹ̀-èdè Sudan látàrí ọ̀pọ̀ èrò nípasẹ̀ ogun tó ń lọ lọ́wọ́.

Àwọn olùrànlọ́wọ́ sísọ lójú eégún pé kòsí epo fún ọkọ̀ Àmbúlànsì, kò tún sí àwọn nǹkan èèlò míràn ní ilé ìwòsàn náà.

Ó kéré tán méjìlá lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ènìyàn ló ti kú láti ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Kẹrin, tí igba lé lẹ́gbẹ̀rún mẹ́rin ènìyàn sì ti farapa bí àjọ èletò ìlera orílẹ̀-èdè Sudan se sọ.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button