Take a fresh look at your lifestyle.

Ààre Buhari Fagilé Ìyànsípò Saratu Umar Gẹ́gẹ́ Bí Olùsàkóso Ìdókoòwò

0 333

Ààrẹ Buhari ti gbé ìgbésẹ̀ akin lójúnà àti mú ìdádúró bá ìyànsípò Saratu umar gẹ́gẹ́ bí alákòsóo ìdókoòwò fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

 

Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí ààrẹ fún ìfọ̀rọ̀léde, Fẹmi Adesina ni ó sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà nínú ìfiléde rẹ̀ ní alẹ́ Ọjọ́bọ̀ (Thursday).

 

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àtakò àti ìfẹ̀hónúhàn ni ó wáyé lórí ìyànsípò Hajia Umar láti ọwọ́ àwọn òsìṣẹ́ àjọ náà léyìí tí wọ́n fi hàn pé arábìnrin náà kò lẹ́tọ̀ọ́ sí ipò náà.

 

Awuye-wuye náà ló mú kí Ààrẹ  Buhari yí ìpinnu rẹ̀ padà, tí ó sì pàsẹ ìyọnípò rẹ̀.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button