Take a fresh look at your lifestyle.

UNIBEN Gbá Ààmì Ẹyẹ Fásítì Tó Dára Jùlọ Ní Ilẹ̀ Áfíríkà Èyí Tó Wáyé Ní Orílẹ̀-èdè Rwanda

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 429

Yunifásítì tí Benin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí gbá Ààmì Ẹyẹ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ilẹ̀ Áfíríkà fún Ọdún 2023 ní Rwanda.

Ìgbákejì Alàkóso tí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga, Ọ̀jọ̀gbọ́n Lilian Salami, tún gbá Ọlá tó gá jù gẹ́gẹ́ bí “Pillar of Education Africa” fún ipá rẹ̀ nínú ìdàgbàsókè ètò-ẹ̀kọ́ ní ilẹ̀ Áfíríkà.

Gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ kàn látí ẹnu àlùkòrò tí Ilé-iṣẹ́ náà, Dr. Benedicta Ehanire ní ọjọ́ Ẹtì ní Benin, àwọn ààmì náà ní a gbà kálẹ̀ ní àpéjọ “1st Africa Education Summit,” tó wáyé ní Yunifásítì tí Rwanda ní Kigali.

Ehanire sọ pé “Yàtọ sí ipá tí ó kò nínú Ìgbìmọ̀ Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Salami tún jẹ́ Ìgbákejì Ààrẹ tí ẹgbẹ́ àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga (Association of African Universities) ní Ghana.”

Ọ̀jọ̀gbọ́n náà ló Ipò rẹ̀ látí rán àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní ilẹ̀ Áfíríkà àtí tí ilẹ̀ Nàìjíríà, pàápà jùlọ́ ilé-ẹ̀kọ́ aṣojú gíga tí Benin (University of Benin).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button