Àjọ elétò ìdìbò orílẹ̀-èdè (INEC), ti fẹ bẹrẹ akojọpọ esi ibo ní Ìpínlẹ̀ Edo, ẹkùn gúsù orílẹ̀-èdè Nàíjíríà.
Àjọ elétò ìdìbò orílẹ̀-èdè INEC sọ pe àwọn ń dúró de esi ibo Ààrẹ àti ti Ilé-ìgbìmọ̀ orilẹ-ede Nàíjíríà ti o waye ni gbogbo àwọn ijọba ìbílẹ̀ mejidinlogun ní ìpínlẹ̀ náà ní ọjọ́ Jímò, ọjọ́ karùndínlọ́gbọ́n, ọdún 2023.
Níbàyí, díẹ̀ nínú àwọn tó wá sàmójútó láti òkè òkun ti wà pẹlu wọn àti ọpọlọpọ awọn oniroyin to n duro lati gba àwọn abajade láti àwọn agbegbe ìjọba ibilẹ wọn.
Ọláyinká Akíntọ́lá
Leave a Reply